Kíkó Àṣà Jọ

Bí a ti ń gbìyànjú láti mú ìdàgbàsókè bá Gbọ̀ngàn John Randle, olùdásílẹ̀ rẹ̀ ti ṣe ìwádìí àwọn ìtàn amúnilọ́kàn tí ó so mọ́ àṣà Yorùbá. Ẹ tẹ̀síwájú láti ka àwọn àpẹẹrẹ èyí.